Sacrifice (Ebọ; Etutu)
Sacrifice (Ebọ; Etutu) Medium: Chinese Bamboo on bond paper Atelewọ ni o hu’run hèùhèù Dia fun Mofẹ́ẹ́ní Tín bẹ láàrín Òsììrí Tín bẹ láàrín ìpọ́njú To wá nlọ rèé k’owó...
View ArticleIbeere Toni: laiye #Ijohun ati #Aye Ode oni
Ojuwo lefi wo asa ila kiko laiye #IJOHUN ati #AIYE_ISIN …..nje odara kamo ko omo wa nila bi???
View ArticleOlojo Ibi Toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alagba Oluwakayode Olamilekan Adekoya Ijeni ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba. Okan pataki ni won je lara awon majekobaje ilu yi, oloye nla niwon...
View ArticleEeto Owe L’esin Oro 4
Mo ki gbogbo wa kaabo si akotun eeto yin, eeto wa owe l’esin oro. Laakoko, mo dupe lowo Olodumare ti o funwa ni oore-ofe lati tun pade loni, leyin igba ti a dagbere fun eeto ni ose to koja. Moki...
View ArticleOgulutu Oro Toni
Hummmmmm mase beru #eniyan ju #Eledumare lo… woo orewa Kosi nkan tenikan o fi enikan Se,gbiyanjuy latile koju ota re loni,jeki o mo wipe Akinkanju eyan nio #nje O mo wipe toba ti nberu eyan...
View ArticleIdile Alayo Toni
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. E wa nkan f’idi...
View ArticleIdajo mi ree…
Leyin gbogbo atotonu awon agbejoro mejeji ati iwadi to peye, ariipe ojebi esun ti a fikan e, nitori na idajo mi ree, ile ejo yi so e sinu: i) igbega; ii) aseyori; iii) idunnu; iv) ayo; v) ire owo; vi)...
View ArticleObara Oturupon/Obara Tiele Corpus by Ifa Chief Priest
Good morning my people, how was your night? Hope it was enjoyed. I wish you all happy new month, may this month bring us everlasting joy and happiness amen. It is OBARA OTURUPON/ OBARA TIELE corpus...
View ArticleGbiyanju lati toju obi i re !
Ojumo to mo wa lonii, ojumo ibukun, ojumo igbega, ojumo aseyori, ojumo ire, ojumo itunu, ojumo ayo, ojumo idunnu ni yoo je fun gbogbo wa lase Edumare(Ase). # AKARA IMORAN : Gbiyanju lati toju obi i...
View ArticleA ku ojumo oooooooo!
Oba to silekun ojo oni, yoo sina ayo fun wa, yoo sina aje fun wa, A ko no seru egbe wa, ire ayo wa ko ni fo wa ru(Ase). #AKARA_IMORAN : Ma se gbo oro okere, gbiyanju lati wadi ohun gbogbo daju, ki o...
View Article#OkeItase2016! Preparation of the World Ikin
Ikin ifa agbaye/world ifa sacred palm but…we dem boys getting it ready for the festival… Yay See more photos after the page break
View ArticleSun re O! Henrietta Kosoko
Hummmmmm Erin wo ajanaku tisun bi Oke eyin ka ile Erin wo porogodo,okoko fo omi okoko danu haaaa sebi eyan Se nku re Oga oooo…….Orun mo kanju Ojo eda oni se ooo
View ArticleOdo Iwoyi – 3
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E wa nkan f’idi le...
View ArticleIdile Alayo Toni 09.06.2016
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. Beeni mo ki...
View ArticleIre otun, ire osi, ire niwa..Iree o
Iree! Apa mejeeji l’eyele fi n ko’ree wo’le. Ire otun, ire osi, ire niwa, ire l’eyin, ire Olokun, ire Olosa, ko mi a da giriri wole to wa wa! Aase!
View ArticleIwure Owuro 12.06.2016
E MAA WI TELE MI : *Ori mi wa gbe mi leke abinu eni. *Ori mi ko ni gbabode ibi. *Oloore mi ko ni ri mi sa *Oluwa so egan mi dogo. *Edumare wa fi ibukun sinu ise mi *Lojo tebi n pa ile, emi ko ni si...
View ArticleArewa Asa Toni
Ayeye Ojo Ibi Iyawa Toyin Adewale Ojo ibi se koko Ojo ibi se pataki eo ni mo Ojo ibi yin saburu,Ododun ni sapo nruwe Ododun ni mariwo yo Ododun la nri omo obi lori ate, emi yin o se opo odun laiye...
View Articleko ko ko. Tani yen o?
Awa ni O! Eyin Wo? Awa Anu,Ire,Iyanu,Owo,OmO, Ayo,Ibukun,Alafia,Igbega,Aseyori,Aabo,Idunu,Itesiwaju, Ojurere Olorun at Emi gigun. Kini e wa o?. Awa lati wa ba iwo ati ebire/ore eyi ti o fe fun ire gbe...
View Article