Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Happy Isese Month

$
0
0

Happy Isese Month to all Ifangelists, our Obas, elders and the Isese Kingdom as we shall soon celebrate the Osun Osogbo Festival! 
Ore Yeye Osun o!
Iya Ijumu Baale Odo;
Iyalode Afon; 
Emi o mo ibi ti Eri n wo lo;
Emi i ba toju 
Ohun rere de Iya mi;
Maa tewo mi gbowo;
Maa tewo mi gba omo; 
Iya mi, ti o ba se mi
Loore maa yo; 
Ladekoju Ore Yeye Osun o;
O gbe’nu Òkun yinbon ide!
Odun ayo la o se!
Aase bi ti n se l’Otu Ife!
Foto: Araba Agboola Awodiran


Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Trending Articles