Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Orúkọ Àpọ́nlé àwọn Obìnrin (Yoruba descriptive female names)

$
0
0

Aya = Wife
Ìyá Afin = Queen
Ayaba = Queen
Yèyé Ọba = Queen mother
Olorì = King’s wife
Omidan =Beautiful woman
Ọmọge = Young fashionable woman
Ìyàwó = Wife
Erelú = Female Chief
Ìyálọjà = Market Leader
Ìyá Àdínnì = Female Muslim Leader
Ìyálájé = Female title (Successful female entrepreneur)

Orúkọ Àpọ́nlé àwọn Obìnrin (Yoruba descriptive female names)

By Adébóyè Adégbénró

 


Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Trending Articles